2017 World Teachers’ Day Celebration

ENGLISH

Educational Initiative for Development in Western Nigeria congratulates all our teachers on the celebration of Teachers ‘ Day today 5th October 2017. To all of us who have ever passed through any school and are now in our respective vocations in life,  we plead with you to please remember those teachers today by appreciating the labour of love showered on you.  “Do Something!” Remember and send a gift especially to those teachers who encouraged you to study hard, correct your errors, forced you to do your homework and prepared you for a successful life.

Is it too much for you and your group of classmates to send a car to your teacher of 25 years who until now is labouring on your children and still cannot afford the comforts of life you now enjoy?

Consider it, be grateful!

This message is from Educational Initiative for Development in Western Nigeria.

 

 

YORUBA

Atótó arére o!

Educational Initiative for Development in Western Nigeria kí gbogbo àwon olùkó wa lónì í tíí se ayeye àyójó ojó àwon olùkó l’ágbàyé é.

Èyí ni láti so fún gbogbo àwa tí a ti lo ilé-ìwé kan tàbí òmíràn láti rántí àwon olùkó wa àti ilé-ìwé tí a lo. Òpò olùkó tó kó wa lódún púpò séyìn kò lè gbé ìgbé ayé ìròrùn tí òpò wa n gbé nísinsìyí, nítorí náà e jé kí á rántí won kí á sì se wón lóore.

Onísé owó, onímótò, onísòwò, òsìsé ìjoba, onísé osù, onísé àdáni, agbasése, òjògbón ilé èkó gíga, e jé kí gbogbo wa wá nnkan sowó sí àwon Ògèdè tí wón wo Kòkó wa yè; bó se owó tó kéré jojo ni, bó se owó goboi ni, bó sì se èbùn náà ni, e jé kí á fi pón won lé. Gbogbo wa la ó j’èrè tí a ó ferè é j’èko.

Ìkéde yìí wá láti Educational Initiative for Development in Western Nigeria.

 

PIDGIN

Educational Initiative for Development in Western Nigeria dey congratulate all our teachers today, World Teachers’ Day.

My country people, today 5th October na payback day for we old teachers o. Make every person wey don go any school before especially primary, remember him old school and old teachers wey don sow for him life, to bless them shikini abi yafunyafun as him pocket gree am. Brother, sister, u be: handworker, trader, transporter, contractor, scholar… anyway wey u go fit make your old teacher jollificate in cash abi na in kind for this period, Do Something! Nothing dey too small to give or do. Remember! At all at all na him bad pass.

This message na from Educational Initiative for Development in Western Nigeria.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *